5“‘Tí ẹnì* kan bá gbọ́ tí wọ́n ń kéde ní gbangba pé kí ẹni tó bá mọ̀ nípa ọ̀rọ̀ kan wá jẹ́rìí sí i,*+ tí ẹni náà sì jẹ́ ẹlẹ́rìí ọ̀rọ̀ náà tàbí tó ṣojú rẹ̀ tàbí tó mọ̀ nípa rẹ̀, àmọ́ tí kò sọ, ó ti ṣẹ̀, yóò sì jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.
17 “Tí ẹnì* kan bá ṣe èyíkéyìí nínú àwọn ohun tí Jèhófà pa láṣẹ pé kí ẹ má ṣe, tó sì tipa bẹ́ẹ̀ ṣẹ̀, bí kò bá tiẹ̀ mọ̀, yóò jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ torí ó ṣì jẹ̀bi.+