Jẹ́nẹ́sísì 30:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Sílípà ìránṣẹ́ Líà sì bí ọmọkùnrin kan fún Jékọ́bù. 11 Líà wá sọ pé: “Ire wọlé dé!” Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Gádì.*+ Jẹ́nẹ́sísì 46:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn ọmọ Gádì+ ni Sífíónì, Hágì, Ṣúnì, Ésíbónì, Érì, Áródì àti Árélì.+ Nọ́ńbà 2:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kí ẹ̀yà Gádì wá tẹ̀ lé wọn; Élíásáfù+ ọmọ Rúẹ́lì ni ìjòyè àwọn ọmọ Gádì. 15 Àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùndínláàádọ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà àti àádọ́ta (45,650).+
10 Sílípà ìránṣẹ́ Líà sì bí ọmọkùnrin kan fún Jékọ́bù. 11 Líà wá sọ pé: “Ire wọlé dé!” Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Gádì.*+
14 Kí ẹ̀yà Gádì wá tẹ̀ lé wọn; Élíásáfù+ ọmọ Rúẹ́lì ni ìjòyè àwọn ọmọ Gádì. 15 Àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùndínláàádọ́ta ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà àti àádọ́ta (45,650).+