Léfítíkù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kí àlùfáà mú lára ọrẹ ọkà náà láti fi ṣe ọrẹ ìṣàpẹẹrẹ,*+ kó mú kó rú èéfín lórí pẹpẹ bí ọrẹ àfinásun tó ní òórùn dídùn* sí Jèhófà.+
9 Kí àlùfáà mú lára ọrẹ ọkà náà láti fi ṣe ọrẹ ìṣàpẹẹrẹ,*+ kó mú kó rú èéfín lórí pẹpẹ bí ọrẹ àfinásun tó ní òórùn dídùn* sí Jèhófà.+