-
Nọ́ńbà 5:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Tí ọkùnrin náà bá ń jowú, tó ń fura pé ìyàwó òun ti dalẹ̀ òun, tí obìnrin náà sì ti sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́ tàbí tí ọkùnrin náà ń jowú, tó ń fura pé ìyàwó òun ti dalẹ̀ òun, àmọ́ tí obìnrin náà kò sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́, 15 kí ọkùnrin náà mú ìyàwó rẹ̀ wá sọ́dọ̀ àlùfáà, kó mú ọrẹ dání fún un, ìyẹ̀fun ọkà bálì tó kún ìdá mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà.* Kó má da òróró sí i, kó má sì fi oje igi tùràrí sórí rẹ̀, torí ọrẹ ọkà owú ni, ọrẹ ọkà tó ń múni rántí ẹ̀bi.
-