Léfítíkù 8:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Lẹ́yìn náà, Mósè sọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé: “Ẹ se+ ẹran náà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, ibẹ̀ sì ni kí ẹ ti jẹ ẹ́ pẹ̀lú búrẹ́dì tó wà nínú apẹ̀rẹ̀ àfiyanni, bí àṣẹ tí mo gbà tó sọ pé, ‘Kí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ jẹ ẹ́.’+
31 Lẹ́yìn náà, Mósè sọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé: “Ẹ se+ ẹran náà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, ibẹ̀ sì ni kí ẹ ti jẹ ẹ́ pẹ̀lú búrẹ́dì tó wà nínú apẹ̀rẹ̀ àfiyanni, bí àṣẹ tí mo gbà tó sọ pé, ‘Kí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ jẹ ẹ́.’+