-
Rúùtù 2:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ìgbà yẹn ni Bóásì dé láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù, ó sì sọ fún àwọn olùkórè náà pé: “Kí Jèhófà wà pẹ̀lú yín.” Wọ́n sì dáhùn pé: “Kí Jèhófà bù kún ọ.”
-
-
Sáàmù 134:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Kí Jèhófà, Aṣẹ̀dá ọ̀run àti ayé,
Bù kún ọ láti Síónì.
-