-
Sáàmù 31:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Mú kí ojú rẹ tàn sára ìránṣẹ́ rẹ.+
Fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ gbà mí sílẹ̀.
-
-
Sáàmù 67:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
67 Ọlọ́run yóò ṣojú rere sí wa, yóò sì bù kún wa;
Yóò mú kí ojú rẹ̀ tàn sí wa lára+ (Sélà)
-