Nọ́ńbà 2:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kí ẹ̀yà Mánásè+ pàgọ́ sí ẹ̀gbẹ́ wọn; Gàmálíẹ́lì+ ọmọ Pédásúrì ni ìjòyè àwọn ọmọ Mánásè. 21 Àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélọ́gbọ̀n ó lé igba (32,200).+
20 Kí ẹ̀yà Mánásè+ pàgọ́ sí ẹ̀gbẹ́ wọn; Gàmálíẹ́lì+ ọmọ Pédásúrì ni ìjòyè àwọn ọmọ Mánásè. 21 Àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ nínú àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélọ́gbọ̀n ó lé igba (32,200).+