Nọ́ńbà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Kí ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Rúbẹ́nì+ wà ní apá gúúsù, ní àwùjọ-àwùjọ;* Élísúrì+ ọmọ Ṣédéúrì ni ìjòyè àwọn ọmọ Rúbẹ́nì. Nọ́ńbà 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Rúbẹ́nì wá gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Élísúrì+ ọmọ Ṣédéúrì sì ni olórí àwùjọ náà.
10 “Kí ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Rúbẹ́nì+ wà ní apá gúúsù, ní àwùjọ-àwùjọ;* Élísúrì+ ọmọ Ṣédéúrì ni ìjòyè àwọn ọmọ Rúbẹ́nì.