-
Léfítíkù 27:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 “‘Ṣékélì ibi mímọ́ ni kí ẹ fi díwọ̀n gbogbo owó náà. Kí ṣékélì náà jẹ́ ogún (20) òṣùwọ̀n gérà.*