-
Léfítíkù 4:22, 23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 “‘Tí ìjòyè+ kan bá ṣẹ̀ láìmọ̀ọ́mọ̀, tó ṣe ọ̀kan nínú gbogbo ohun tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ pa láṣẹ pé kí ẹ má ṣe, tí ìjòyè náà sì jẹ̀bi, 23 tàbí tó wá mọ̀ pé òun ti ṣe ohun tó lòdì sí àṣẹ náà, kó mú akọ ọmọ ewúrẹ́ tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá wá láti fi ṣe ọrẹ.
-