Nọ́ńbà 2:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 “Kí ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Dánì wà ní apá àríwá, ní àwùjọ-àwùjọ;* Áhíésérì+ ọmọ Ámíṣádáì ni ìjòyè àwọn ọmọ Dánì. Nọ́ńbà 10:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Dánì wá gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* àwọn ni wọ́n wà lẹ́yìn tí wọ́n ń ṣọ́ gbogbo ibùdó náà. Áhíésérì+ ọmọ Ámíṣádáì ni olórí àwùjọ náà.
25 “Kí ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Dánì wà ní apá àríwá, ní àwùjọ-àwùjọ;* Áhíésérì+ ọmọ Ámíṣádáì ni ìjòyè àwọn ọmọ Dánì.
25 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Dánì wá gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* àwọn ni wọ́n wà lẹ́yìn tí wọ́n ń ṣọ́ gbogbo ibùdó náà. Áhíésérì+ ọmọ Ámíṣádáì ni olórí àwùjọ náà.