-
Ẹ́kísódù 25:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Fìtílà méje ni kí o ṣe sórí ọ̀pá náà, tí wọ́n bá sì tan àwọn fìtílà náà, iná wọn á mọ́lẹ̀ síwájú ọ̀pá náà.+
-
-
Léfítíkù 24:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n gbé ògidì òróró ólífì tí wọ́n fún wá sọ́dọ̀ rẹ láti máa fi tan iná, kí àwọn fìtílà náà lè máa wà ní títàn nígbà gbogbo.+
-