Ẹ́kísódù 37:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó wá fi ògidì wúrà ṣe ọ̀pá fìtílà.+ Iṣẹ́ ọnà tó fi òòlù ṣe ni ọ̀pá fìtílà náà. Ìsàlẹ̀ rẹ̀, ọ̀pá rẹ̀, àwọn iṣẹ́ ọnà rẹ̀, àwọn kókó rubutu rẹ̀ àti àwọn ìtànná rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan ṣoṣo.+
17 Ó wá fi ògidì wúrà ṣe ọ̀pá fìtílà.+ Iṣẹ́ ọnà tó fi òòlù ṣe ni ọ̀pá fìtílà náà. Ìsàlẹ̀ rẹ̀, ọ̀pá rẹ̀, àwọn iṣẹ́ ọnà rẹ̀, àwọn kókó rubutu rẹ̀ àti àwọn ìtànná rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan ṣoṣo.+