Ẹ́kísódù 38:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àwọn nǹkan yìí ni wọ́n kà pé ó wà nínú àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ Ẹ̀rí.+ Mósè ló pàṣẹ pé kí àwọn ọmọ Léfì+ kà á, kí Ítámárì ọmọ àlùfáà Áárónì sì darí wọn.+ Nọ́ńbà 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Jẹ́ kí ẹ̀yà Léfì+ wá síwájú, kí o sì ní kí wọ́n dúró níwájú àlùfáà Áárónì, kí wọ́n máa ṣe ìránṣẹ́+ fún un. Nọ́ńbà 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Kí wọ́n máa bójú tó gbogbo ohun èlò+ àgọ́ ìpàdé, kí wọ́n sì máa ṣe iṣẹ́ tó jẹ mọ́ àgọ́ ìjọsìn,+ èyí ni ojúṣe wọn fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.
21 Àwọn nǹkan yìí ni wọ́n kà pé ó wà nínú àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ Ẹ̀rí.+ Mósè ló pàṣẹ pé kí àwọn ọmọ Léfì+ kà á, kí Ítámárì ọmọ àlùfáà Áárónì sì darí wọn.+
6 “Jẹ́ kí ẹ̀yà Léfì+ wá síwájú, kí o sì ní kí wọ́n dúró níwájú àlùfáà Áárónì, kí wọ́n máa ṣe ìránṣẹ́+ fún un.
8 Kí wọ́n máa bójú tó gbogbo ohun èlò+ àgọ́ ìpàdé, kí wọ́n sì máa ṣe iṣẹ́ tó jẹ mọ́ àgọ́ ìjọsìn,+ èyí ni ojúṣe wọn fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.