-
Nọ́ńbà 8:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Bí o ṣe máa wẹ̀ wọ́n mọ́ nìyí: Wọ́n omi ìwẹ̀mọ́ ẹ̀ṣẹ̀ sí wọn lára, kí wọ́n sì fi abẹ fá gbogbo irun ara wọn, kí wọ́n fọ aṣọ wọn, kí wọ́n sì wẹ ara wọn mọ́.+
-