Nọ́ńbà 8:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Kí àwọn ọmọ Léfì gbé ọwọ́ wọn lé orí àwọn akọ màlúù+ náà. Lẹ́yìn náà, kí wọ́n fi ọ̀kan rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, kí wọ́n sì fi ìkejì rú ẹbọ sísun sí Jèhófà láti ṣe ètùtù+ fún àwọn ọmọ Léfì.
12 “Kí àwọn ọmọ Léfì gbé ọwọ́ wọn lé orí àwọn akọ màlúù+ náà. Lẹ́yìn náà, kí wọ́n fi ọ̀kan rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, kí wọ́n sì fi ìkejì rú ẹbọ sísun sí Jèhófà láti ṣe ètùtù+ fún àwọn ọmọ Léfì.