Nọ́ńbà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n ní kí gbogbo adẹ́tẹ̀+ jáde kúrò nínú ibùdó àti gbogbo ẹni tí nǹkan ń dà lára rẹ̀+ pẹ̀lú gbogbo ẹni tí òkú èèyàn*+ ti sọ di aláìmọ́.
2 “Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n ní kí gbogbo adẹ́tẹ̀+ jáde kúrò nínú ibùdó àti gbogbo ẹni tí nǹkan ń dà lára rẹ̀+ pẹ̀lú gbogbo ẹni tí òkú èèyàn*+ ti sọ di aláìmọ́.