-
Ẹ́kísódù 12:46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 Inú ilé kan ni kí ẹ ti jẹ ẹ́. Ẹ ò gbọ́dọ̀ mú ìkankan nínú ẹran náà kúrò nínú ilé lọ síta, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ fọ́ ìkankan nínú egungun rẹ̀.+
-