Ẹ́kísódù 12:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘Kí wọ́n jẹ ẹran náà lálẹ́ yìí.+ Kí wọ́n yan án lórí iná, kí wọ́n sì jẹ ẹ́ pẹ̀lú búrẹ́dì aláìwú+ àti ewébẹ̀ kíkorò.+
8 “‘Kí wọ́n jẹ ẹran náà lálẹ́ yìí.+ Kí wọ́n yan án lórí iná, kí wọ́n sì jẹ ẹ́ pẹ̀lú búrẹ́dì aláìwú+ àti ewébẹ̀ kíkorò.+