Ẹ́kísódù 13:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ọwọ̀n ìkùukùu* náà kì í kúrò níwájú àwọn èèyàn náà lọ́sàn-án, ọwọ̀n iná kì í sì í kúrò lóru.+ Nehemáyà 9:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 síbẹ̀ ìwọ, nínú àánú ńlá rẹ, o ò kọ̀ wọ́n sílẹ̀ nínú aginjù.+ Ọwọ̀n ìkùukùu* kò kúrò lórí wọn ní ọ̀sán láti máa darí wọn ní ọ̀nà wọn, ọwọ̀n iná* kò sì kúrò ní òru láti fún wọn ní ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀nà tí wọ́n máa gbà.+
19 síbẹ̀ ìwọ, nínú àánú ńlá rẹ, o ò kọ̀ wọ́n sílẹ̀ nínú aginjù.+ Ọwọ̀n ìkùukùu* kò kúrò lórí wọn ní ọ̀sán láti máa darí wọn ní ọ̀nà wọn, ọwọ̀n iná* kò sì kúrò ní òru láti fún wọn ní ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀nà tí wọ́n máa gbà.+