ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 2:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 “Nígbà tí ẹ bá ń gbé àgọ́ ìpàdé kúrò,+ àgọ́ àwọn ọmọ Léfì ni kó wà láàárín àwọn àgọ́ yòókù.

      “Bí wọ́n bá ṣe pàgọ́ náà ni kí wọ́n ṣe tẹ̀ léra tí wọ́n bá ń rìnrìn àjò,+ kí kálukú wà ní àyè rẹ̀, bí wọ́n ṣe pín ẹ̀yà wọn ní mẹ́ta-mẹ́ta.

  • Nọ́ńbà 3:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ẹ̀yìn àgọ́ ìjọsìn+ lápá ìwọ̀ oòrùn ni ìdílé àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì pàgọ́ sí.

  • Nọ́ńbà 3:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Apá gúúsù àgọ́ ìjọsìn+ ni ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì pàgọ́ sí.

  • Nọ́ńbà 3:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Súríélì ọmọ Ábíháílì ni ìjòyè agbo ilé nínú àwọn ìdílé Mérárì. Apá àríwá àgọ́ ìjọsìn+ ni wọ́n pàgọ́ sí.

  • Nọ́ńbà 3:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Mósè àti Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ ló pàgọ́ síwájú àgọ́ ìjọsìn lápá ìlà oòrùn, níwájú àgọ́ ìpàdé lápá ibi tí oòrùn ti ń yọ. Ojúṣe wọn sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ni pé kí wọ́n máa bójú tó ibi mímọ́. Tí ẹnikẹ́ni tí kò lẹ́tọ̀ọ́ sí i* bá sún mọ́ tòsí, ṣe ni wọ́n máa pa á.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́