Nọ́ńbà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Kí ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Júdà pàgọ́ sí ìlà oòrùn, lápá ibi tí oòrùn ti ń yọ, ní àwùjọ-àwùjọ;* Náṣónì+ ọmọ Ámínádábù ni ìjòyè àwọn ọmọ Júdà.
3 “Kí ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Júdà pàgọ́ sí ìlà oòrùn, lápá ibi tí oòrùn ti ń yọ, ní àwùjọ-àwùjọ;* Náṣónì+ ọmọ Ámínádábù ni ìjòyè àwọn ọmọ Júdà.