Nọ́ńbà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní aginjù Sínáì,+ nínú àgọ́ ìpàdé,+ ní ọjọ́ kìíní oṣù kejì, ọdún kejì tí wọ́n kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Ó sọ pé:
1 Jèhófà bá Mósè sọ̀rọ̀ ní aginjù Sínáì,+ nínú àgọ́ ìpàdé,+ ní ọjọ́ kìíní oṣù kejì, ọdún kejì tí wọ́n kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Ó sọ pé: