ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 12:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Àwọn èèyàn náà wá kúrò ní Hásérótì,+ wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í pàgọ́ sí aginjù Páránì.+

  • Nọ́ńbà 13:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Wọ́n sì pa dà sọ́dọ̀ Mósè àti Áárónì àti gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní aginjù Páránì, ní Kádéṣì.+ Wọ́n jábọ̀ fún gbogbo àpéjọ náà, wọ́n sì fi àwọn èso ilẹ̀ náà hàn wọ́n.

  • Diutarónómì 1:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 1 Èyí ni àwọn ọ̀rọ̀ tí Mósè bá gbogbo Ísírẹ́lì sọ ní agbègbè Jọ́dánì nínú aginjù, ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú níwájú Súfù, láàárín Páránì, Tófélì, Lábánì, Hásérótì àti Dísáhábù. 2 Ìrìn ọjọ́ mọ́kànlá (11) ni láti Hórébù sí Kadeṣi-bánéà+ tí wọ́n bá gba ọ̀nà Òkè Séírì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́