ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Mósè ń bójú tó agbo ẹran Jẹ́tírò+ bàbá ìyàwó rẹ̀ tó jẹ́ àlùfáà Mídíánì. Nígbà tó ń da agbo ẹran náà lọ sí apá ìwọ̀ oòrùn aginjù, ó dé Hórébù, òkè Ọlọ́run tòótọ́.+

  • Ẹ́kísódù 19:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Mósè wá gòkè lọ bá Ọlọ́run tòótọ́, Jèhófà sì pè é láti òkè náà+ pé: “Ohun tí ìwọ yóò sọ fún ilé Jékọ́bù àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nìyí,

  • Ẹ́kísódù 24:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ògo Jèhófà+ ò kúrò lórí Òkè Sínáì,+ ìkùukùu náà sì bò ó fún ọjọ́ mẹ́fà. Ní ọjọ́ keje, ó pe Mósè látinú ìkùukùu náà.

  • Diutarónómì 5:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Jèhófà Ọlọ́run wa bá wa dá májẹ̀mú kan ní Hórébù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́