Nọ́ńbà 1:52 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 “Kí ọmọ Ísírẹ́lì kọ̀ọ̀kan pa àgọ́ rẹ̀ sí ibi tí wọ́n yàn fún un, ọkùnrin kọ̀ọ̀kan níbi tí wọ́n pín àwọn ẹ̀yà sí ní mẹ́ta-mẹ́ta,*+ ní àwùjọ-àwùjọ.*
52 “Kí ọmọ Ísírẹ́lì kọ̀ọ̀kan pa àgọ́ rẹ̀ sí ibi tí wọ́n yàn fún un, ọkùnrin kọ̀ọ̀kan níbi tí wọ́n pín àwọn ẹ̀yà sí ní mẹ́ta-mẹ́ta,*+ ní àwùjọ-àwùjọ.*