Diutarónómì 16:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Kí o yan àwọn onídàájọ́+ àti àwọn olórí fún ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan ní gbogbo ìlú* tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ, kí wọ́n sì máa fi òdodo ṣèdájọ́ àwọn èèyàn náà.
18 “Kí o yan àwọn onídàájọ́+ àti àwọn olórí fún ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan ní gbogbo ìlú* tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ, kí wọ́n sì máa fi òdodo ṣèdájọ́ àwọn èèyàn náà.