Nọ́ńbà 21:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn èèyàn náà wá ń sọ̀rọ̀ sí Ọlọ́run àti Mósè+ pé: “Kí ló dé tí ẹ kó wa kúrò ní Íjíbítì ká lè wá kú sínú aginjù? Kò sí oúnjẹ, kò sí omi,+ a* sì ti kórìíra oúnjẹ játijàti+ yìí.”*
5 Àwọn èèyàn náà wá ń sọ̀rọ̀ sí Ọlọ́run àti Mósè+ pé: “Kí ló dé tí ẹ kó wa kúrò ní Íjíbítì ká lè wá kú sínú aginjù? Kò sí oúnjẹ, kò sí omi,+ a* sì ti kórìíra oúnjẹ játijàti+ yìí.”*