Ẹ́kísódù 33:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Gbàrà tí Mósè bá ti wọnú àgọ́, ọwọ̀n ìkùukùu*+ máa sọ̀ kalẹ̀, á sì dúró sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ nígbà tí Ọlọ́run bá ń bá Mósè sọ̀rọ̀.+ Nọ́ńbà 12:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà wá sọ̀ kalẹ̀ wá nínú ọwọ̀n ìkùukùu,*+ ó dúró ní ẹnu ọ̀nà àgọ́, ó sì pe Áárónì àti Míríámù. Àwọn méjèèjì sì bọ́ síwájú. Diutarónómì 31:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà wá fara hàn ní àgọ́ náà nínú ọwọ̀n ìkùukùu,* ọwọ̀n ìkùukùu náà sì dúró ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ náà.+
9 Gbàrà tí Mósè bá ti wọnú àgọ́, ọwọ̀n ìkùukùu*+ máa sọ̀ kalẹ̀, á sì dúró sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ nígbà tí Ọlọ́run bá ń bá Mósè sọ̀rọ̀.+
5 Jèhófà wá sọ̀ kalẹ̀ wá nínú ọwọ̀n ìkùukùu,*+ ó dúró ní ẹnu ọ̀nà àgọ́, ó sì pe Áárónì àti Míríámù. Àwọn méjèèjì sì bọ́ síwájú.
15 Jèhófà wá fara hàn ní àgọ́ náà nínú ọwọ̀n ìkùukùu,* ọwọ̀n ìkùukùu náà sì dúró ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ náà.+