Sáàmù 99:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó ń bá wọn sọ̀rọ̀ látinú ọwọ̀n ìkùukùu.*+ Wọ́n pa àwọn ìránnilétí rẹ̀ àti àṣẹ tó fún wọn mọ́.+