Máàkù 9:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Jòhánù sọ fún un pé: “Olùkọ́, a rí ẹnì kan tó ń fi orúkọ rẹ lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, a sì gbìyànjú láti dá a dúró, torí kì í tẹ̀ lé wa.”+
38 Jòhánù sọ fún un pé: “Olùkọ́, a rí ẹnì kan tó ń fi orúkọ rẹ lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde, a sì gbìyànjú láti dá a dúró, torí kì í tẹ̀ lé wa.”+