-
Jẹ́nẹ́sísì 31:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Nígbà kan tí àwọn ẹran fẹ́ gùn, mo lá àlá, mo wòkè, mo sì rí i pé àwọn òbúkọ abilà, aláwọ̀ tó-tò-tó àti àwọn tó lámì lára+ ń gun àwọn ẹran náà. 11 Áńgẹ́lì Ọlọ́run tòótọ́ pè mí lójú àlá, ó ní, ‘Jékọ́bù!’ mo sì fèsì pé, ‘Èmi nìyí.’
-