Hébérù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó jẹ́ olóòótọ́ sí Ẹni tó yàn án,+ bí Mósè náà ṣe jẹ́ ní gbogbo ilé Ẹni yẹn.+ Hébérù 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mósè jẹ́ ìránṣẹ́ olóòótọ́ ní gbogbo ilé Ẹni yẹn, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí* àwọn ohun tí a máa sọ lẹ́yìn náà,