2 Kíróníkà 26:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àmọ́ inú bí Ùsáyà nígbà tí àwo tó fẹ́ fi sun tùràrí ti wà lọ́wọ́ rẹ̀;+ bí inú ṣe ń bí i sí àwọn àlùfáà lọ́wọ́, ẹ̀tẹ̀+ yọ níwájú orí rẹ̀ níṣojú àwọn àlùfáà nínú ilé Jèhófà lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ tùràrí.
19 Àmọ́ inú bí Ùsáyà nígbà tí àwo tó fẹ́ fi sun tùràrí ti wà lọ́wọ́ rẹ̀;+ bí inú ṣe ń bí i sí àwọn àlùfáà lọ́wọ́, ẹ̀tẹ̀+ yọ níwájú orí rẹ̀ níṣojú àwọn àlùfáà nínú ilé Jèhófà lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ tùràrí.