-
2 Sámúẹ́lì 10:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Nígbà tó yá, àwọn ọmọ Ámónì rí i pé àwọn ti di ẹni ìkórìíra lójú Dáfídì, torí náà àwọn ọmọ Ámónì ránṣẹ́ sí àwọn ará Síríà tó wà ní Bẹti-réhóbù+ àti àwọn ará Síríà tó wà ní Sóbà,+ wọ́n sì háyà ọ̀kẹ́ kan (20,000) àwọn ọmọ ogun tó ń fẹsẹ̀ rìn lọ́dọ̀ wọn; àti lọ́dọ̀ ọba Máákà,+ ẹgbẹ̀rún kan (1,000) ọkùnrin; àti láti Íṣítóbù,* ẹgbẹ̀rún méjìlá (12,000) ọkùnrin.+
-
-
2 Sámúẹ́lì 10:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àwọn ọmọ Ámónì jáde lọ, wọ́n sì tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ ní àtiwọ ẹnubodè ìlú, àmọ́ àwọn ará Síríà tó wà ní Sóbà àti ní Réhóbù pẹ̀lú Íṣítóbù* àti Máákà wà lórí pápá.
-