Nọ́ńbà 10:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Júdà ló kọ́kọ́ gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Náṣónì+ ọmọ Ámínádábù sì ni olórí àwùjọ náà.
14 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Júdà ló kọ́kọ́ gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Náṣónì+ ọmọ Ámínádábù sì ni olórí àwùjọ náà.