ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 1:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Àmọ́ àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì ò lé àwọn ará Jébúsì tó ń gbé Jerúsálẹ́mù kúrò, torí náà, àwọn ará Jébúsì ṣì ń bá àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì gbé ní Jerúsálẹ́mù títí dòní.+

  • 2 Sámúẹ́lì 5:6, 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ọba àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ jáde lọ sí Jerúsálẹ́mù láti lọ gbéjà ko àwọn ará Jébúsì+ tó ń gbé ilẹ̀ náà. Wọ́n pẹ̀gàn Dáfídì pé: “O ò ní wọ ibí yìí! Kódà àwọn afọ́jú àti àwọn arọ ló máa lé ọ dà nù.” Èrò wọn ni pé, ‘Dáfídì ò ní wọ ibí yìí.’+ 7 Síbẹ̀, Dáfídì gba ibi ààbò Síónì, èyí tó wá di Ìlú Dáfídì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́