-
Nọ́ńbà 14:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Àwọn ọkùnrin tí Mósè rán lọ ṣe amí ilẹ̀ náà, tí wọ́n mú ìròyìn burúkú wá nípa ilẹ̀ náà,+ tí wọ́n sì wá mú kí gbogbo àpéjọ náà máa kùn sí i,
-