Diutarónómì 1:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Àmọ́ pẹ̀lú gbogbo èyí, ẹ ò gba Jèhófà Ọlọ́run yín gbọ́,+ 33 ẹni tó ń ṣáájú yín lójú ọ̀nà, láti wá ibi tí ẹ lè pàgọ́ sí. Ó ń fara hàn yín nípasẹ̀ iná ní òru àti nípasẹ̀ ìkùukùu* ní ọ̀sán, láti fi ọ̀nà tí ẹ máa gbà hàn yín.+
32 Àmọ́ pẹ̀lú gbogbo èyí, ẹ ò gba Jèhófà Ọlọ́run yín gbọ́,+ 33 ẹni tó ń ṣáájú yín lójú ọ̀nà, láti wá ibi tí ẹ lè pàgọ́ sí. Ó ń fara hàn yín nípasẹ̀ iná ní òru àti nípasẹ̀ ìkùukùu* ní ọ̀sán, láti fi ọ̀nà tí ẹ máa gbà hàn yín.+