Nọ́ńbà 11:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 A ò jẹ́ gbàgbé ẹja tí a máa ń jẹ lọ́fẹ̀ẹ́ nílẹ̀ Íjíbítì àti kùkúńbà,* bàrà olómi, ewébẹ̀ líìkì, àlùbọ́sà àti ááyù!+
5 A ò jẹ́ gbàgbé ẹja tí a máa ń jẹ lọ́fẹ̀ẹ́ nílẹ̀ Íjíbítì àti kùkúńbà,* bàrà olómi, ewébẹ̀ líìkì, àlùbọ́sà àti ááyù!+