-
Diutarónómì 9:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, àwọn èèyàn tó wà ní ilẹ̀ tí o ti mú wa kúrò lè máa sọ pé: “Jèhófà ò lè mú wọn dé ilẹ̀ tó ṣèlérí pé òun máa fún wọn, torí náà, ó mú wọn wá sínú aginjù kó lè pa wọ́n torí ó kórìíra wọn.”+
-