-
Nọ́ńbà 26:64Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
64 Àmọ́ ìkankan nínú wọn kò sí lára àwọn tí Mósè àti àlùfáà Áárónì forúkọ wọn sílẹ̀ nígbà tí wọ́n ka iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní aginjù Sínáì.+
-
-
Diutarónómì 1:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 ‘Ìkankan nínú àwọn èèyàn yìí tí wọ́n wà lára ìran búburú yìí kò ní rí ilẹ̀ dáradára tí mo búra pé màá fún àwọn bàbá yín,+
-