1 Kọ́ríńtì 10:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn nǹkan yìí di àpẹẹrẹ fún wa, kí àwọn ohun tó ń ṣeni léṣe má bàa máa wu àwa náà, bó ṣe wù wọ́n.+ 1 Kọ́ríńtì 10:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bákan náà, kí ẹ má ṣe máa kùn, bí àwọn kan nínú wọn ṣe kùn,+ tí apanirun sì pa wọ́n.+ Júùdù 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ mọ gbogbo èyí, mo fẹ́ rán yín létí pé lẹ́yìn tí Jèhófà* ti gba àwọn èèyàn kan là kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ó pa àwọn tí kò ní ìgbàgbọ́ run.+
6 Àwọn nǹkan yìí di àpẹẹrẹ fún wa, kí àwọn ohun tó ń ṣeni léṣe má bàa máa wu àwa náà, bó ṣe wù wọ́n.+
5 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ mọ gbogbo èyí, mo fẹ́ rán yín létí pé lẹ́yìn tí Jèhófà* ti gba àwọn èèyàn kan là kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ó pa àwọn tí kò ní ìgbàgbọ́ run.+