ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 7:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 “‘Tí ohun tó bá fi rúbọ bá jẹ́ ti ẹ̀jẹ́+ tàbí ọrẹ àtinúwá,+ ọjọ́ tó bá mú ọrẹ rẹ̀ wá ni kó jẹ ẹ́, kó sì jẹ ohun tó bá ṣẹ́ kù lára rẹ̀ ní ọjọ́ kejì.

  • Léfítíkù 22:18, 19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 “Sọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ àti gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Tí ọmọ Ísírẹ́lì kan tàbí àjèjì kan ní Ísírẹ́lì bá mú ẹran ẹbọ sísun+ wá fún Jèhófà kó lè fi san ẹ̀jẹ́ rẹ̀ tàbí kó lè fi ṣe ọrẹ àtinúwá,+ 19 akọ ẹran tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá+ ni kó mú wá látinú ọ̀wọ́ ẹran, àwọn ọmọ àgbò tàbí àwọn ewúrẹ́ kó lè rí ìtẹ́wọ́gbà.

  • Léfítíkù 22:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 “‘Tí ẹnì kan bá mú ẹran ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ wá fún Jèhófà kó lè fi san ẹ̀jẹ́ tàbí kó lè fi ṣe ọrẹ àtinúwá, ẹran tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá ni kó mú wá látinú ọ̀wọ́ ẹran tàbí agbo ẹran, kó lè rí ìtẹ́wọ́gbà. Ẹran náà ò gbọ́dọ̀ ní àbùkù kankan.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́