Léfítíkù 7:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Tí ohun tó bá fi rúbọ bá jẹ́ ti ẹ̀jẹ́+ tàbí ọrẹ àtinúwá,+ ọjọ́ tó bá mú ọrẹ rẹ̀ wá ni kó jẹ ẹ́, kó sì jẹ ohun tó bá ṣẹ́ kù lára rẹ̀ ní ọjọ́ kejì.
16 “‘Tí ohun tó bá fi rúbọ bá jẹ́ ti ẹ̀jẹ́+ tàbí ọrẹ àtinúwá,+ ọjọ́ tó bá mú ọrẹ rẹ̀ wá ni kó jẹ ẹ́, kó sì jẹ ohun tó bá ṣẹ́ kù lára rẹ̀ ní ọjọ́ kejì.