Nọ́ńbà 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó Rúbẹ́nì wá gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Élísúrì+ ọmọ Ṣédéúrì sì ni olórí àwùjọ náà.