-
Nọ́ńbà 28:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Bákan náà, kí ẹ mú ọmọ ewúrẹ́ kan wá láti fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ sí Jèhófà, ní àfikún sí ẹbọ sísun ìgbà gbogbo àti ọrẹ ohun mímu rẹ̀.
-