ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 4:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 “‘Àmọ́ tó bá jẹ́ ọ̀dọ́ àgùntàn ló fẹ́ mú wá láti fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, abo ọ̀dọ́ àgùntàn tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá ni kó mú wá.

  • Léfítíkù 4:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Kó yọ gbogbo ọ̀rá rẹ̀ bí wọ́n ṣe ń yọ ọ̀rá ọmọ àgbò tí wọ́n fi ṣe ẹbọ ìrẹ́pọ̀, kí àlùfáà sì mú kó rú èéfín lórí pẹpẹ, lórí àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà;+ kí àlùfáà sì ṣe ètùtù fún un torí ẹ̀ṣẹ̀ tó dá, yóò sì rí ìdáríjì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́