Ẹ́kísódù 31:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kí ẹ pa Sábáàtì mọ́, torí ohun mímọ́ ló jẹ́ fún yín.+ Ṣe ni kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá sọ ọ́ di aláìmọ́. Tí ẹnikẹ́ni bá ṣiṣẹ́ kankan lọ́jọ́ náà, kí ẹ pa ẹni* náà, kí ẹ lè mú un kúrò nínú àwọn èèyàn rẹ̀.+
14 Kí ẹ pa Sábáàtì mọ́, torí ohun mímọ́ ló jẹ́ fún yín.+ Ṣe ni kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá sọ ọ́ di aláìmọ́. Tí ẹnikẹ́ni bá ṣiṣẹ́ kankan lọ́jọ́ náà, kí ẹ pa ẹni* náà, kí ẹ lè mú un kúrò nínú àwọn èèyàn rẹ̀.+